Isaiah 65:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti òwúrọ̀ di alẹ́, mo na ọwọ́ mi sí àwọn ọlọ̀tẹ̀ eniyan; àwọn tí wọn ń rìn ní ọ̀nà tí kò dára, tí wọn ń tẹ̀lé èrò ọkàn wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ni gbogbo ọjọ ni mo ti na ọwọ́ mi si awọn ọlọtẹ̀ enia, ti nrìn li ọ̀na ti kò dara, nipa ìro ara wọn;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ọjọ́ ni mo ti nawọ́ mi síta sí àwọn ènìyàn ọlọ́rùn líle, tí wọn ń rìn lọ́nà tí kò dára, tí wọ́n sì gbáralé èrò ara wọn