Isaiah 65:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
tí wọn ń ṣe ohun tí yóo mú mi bínú, níṣojú mi, nígbà gbogbo. Wọ́n ń rúbọ ninu oríṣìíríṣìí ọgbà, wọ́n ń sun turari lórí bíríkì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia ti o nṣọ́ mi ni inu nigbagbogbo kàn mi loju; ti nrubọ ninu agbàla, ti nwọn si nfi turari jona lori pẹpẹ briki.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àwọn ènìyàn tí wọ́n bí mi nínú nígbà gbogbo lójú ara mi gan an, wọ́n ń rúbọ nínú ọgbà wọ́n sì ń ṣun tùràrí lóríi pẹpẹ bíríkì;