Isaiah 66:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé iná ni OLUWA yóo fi ṣe ìdájọ́, idà ni yóo fi ṣe ìdájọ́ fún gbogbo eniyan; àwọn tí OLUWA yóo fi idà pa yóo sì pọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Oluwa yio fi iná ati idà rẹ̀ ṣe idajọ gbogbo ẹran-ara; awọn okú Oluwa yio si pọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pẹ̀lú iná àti idà ni OLÚWA yóò ṣe ìdájọ́ lóríi gbogbo ènìyàn, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn tí OLÚWA yóò pa.