Isaiah 66:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ gbọ́ ariwo ninu ìlú, ẹ gbọ́ ohùn kan láti inú Tẹmpili, ohùn OLUWA ni, ó ń san ẹ̀san fún àwọn ọ̀tá rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohùn ariwo lati inu ilu wá, ohùn lati inu tempili wá, ohùn Oluwa ti nsan ẹ̀san fun awọn ọta rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbọ́ rògbòdìyàn n nì láti ìlú wá, gbọ́ ariwo náà láti tẹ́ḿpìlì wá! Ariwo tí OLÚWA ní í ṣe tí ó ń san án fún àwọn ọ̀ta rẹ̀ ohun tí ó tọ́ sí wọn.