Isaiah 8:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ẹ gbìmọ̀ pọ̀ ìmọ̀ yín yóo di òfo. Ohun yòówù tí ẹ lè sọ, àpérò yín yóo di asán. Nítorí pé Ọlọrun wà pẹlu wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ gbìmọ pọ̀ yio si di asan; ẹ sọ̀rọ na, ki yio si duro: nitoripe Ọlọrun wà pẹlu wa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ hun ète yín, yóò di títúká. Ẹ gbérò ètò náà, ṣùgbọ́n kì yóò dúró, nítorí Ọlọ́run wà pẹ̀lúu wa.