Isaiah 8:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Di ẹ̀rí náà, fi èdìdì di ẹ̀kọ́ náà láàrin àwọn ọmọ ẹ̀yìn mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Di ẹri na, fi edídi di ofin na lãrin awọn ọmọ-ẹhin mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Di májẹ̀mú náà kí o sì fi èdìdì di òfin náà láàrin àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mi.