Isaiah 8:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn óo bojú wo ilẹ̀, kìkì ìdààmú ati òkùnkùn ati ìṣúdudu ati ìnira ni wọn óo rí. A óo sì sọ wọ́n sinu òkùnkùn biribiri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o si wò ilẹ, si kiyesi i, iyọnu ati okùnkun, iṣuju irora: a o si le wọn lọ sinu okùnkun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wọn yóò síjú wolẹ̀, wọn yóò sì rí ìpọ́njú, òkùnkùn àti ìpòrúúrù tí ó bani lẹ́rù, a ó sì sọ wọ́n sínú òkùnkùn biribiri.