Isaiah 8:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Nítorí pé àwọn eniyan wọnyi kọ omi Ṣiloa tí ń ṣàn wẹ́rẹ́wẹ́rẹ́ sílẹ̀, wọ́n wá ń gbọ̀n jìnnìjìnnì níwájú Resini ati ọmọ Remalaya,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Niwọn bi enia yi ti kọ̀ omi Ṣiloa ti nṣàn jẹjẹ silẹ, ti nwọn si nyọ̀ ninu Resini ati ọmọ Remaliah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé àwọn ènìyàn ti kọ omi Ṣílóà tí ń ṣàn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ tí wọ́n sì láyọ̀ lórí Réṣínì àti ọmọ Rẹ̀málíà,