Isaiah 8:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí náà, ẹ wò ó, OLUWA yóo gbé ọba Asiria ati gbogbo ògo rẹ̀ dìde wá bá wọn, yóo sì bò wọ́n mọ́lẹ̀ bí omi odò Yufurate, tí ó kún àkúnya, tí ó sì kọjá bèbè rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ nitorina kiyesi i, Oluwa nfà omi odò ti o le, ti o si pọ̀, wá sori wọn, ani ọba Assiria ati gbogbo ogo rẹ̀; yio si wá sori gbogbo ọ̀na odò rẹ̀, yio si gun ori gbogbo bèbe rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
fún ìdí èyí, OLÚWA fẹ́ mú wá sóríi wọn agbára ìkún omi odò ọba Ásíríà àti ògo rẹ̀ yóò sì bo gbogbo àyasíi rẹ̀ gbogbo bèbè di bíbò mọ́lẹ̀

Recommended Reading