Isaiah 9:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà OLUWA ti gbé ọ̀tá dìde sí wọn: Ó ti rú àwọn ọ̀tá wọn sókè sí wọn:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina li Oluwa yio gbe awọn aninilara Resini dide si i, yio si dá awọn ọtá rẹ̀ pọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n OLÚWA fún àwọn ọ̀ta Réṣínì ní agbára láti dojúkọ wọ́n ó sì ti rú àwọn ọ̀ta wọn ṣókè.