Isaiah 9:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Siria láti ìhà ìlà oòrùn, ati àwọn ará Filistia láti ìhà ìwọ̀ oòrùn; wọn óo gbé Israẹli mì. Sibẹsibẹ inú OLUWA kò rọ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò dá ọwọ́ ìjà rẹ̀ dúró.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ara Siria niwaju, ati awọn Filistini lẹhin: nwọn o si fi gbogbo ẹnu jẹ Israeli run. Ni gbogbo eyi ibinu rẹ̀ kò yi kuro, ṣugbọn ọwọ́ rẹ̀ nà jade sibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn Árámínì láti ìlà-oòrùn àti Fílístínì láti ìwọ̀ oòrùn wọ́n si fi gbogbo ẹnu jẹ́ Ìsirẹli run Ní gbogbo èyí ìbínú un rẹ̀ kò yí kúrò Ṣùgbọ́n ọwọ́ rẹ̀ nà jáde ṣíbẹ̀.

Recommended Reading