Isaiah 9:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Sibẹsibẹ àwọn ọmọ Israẹli kò pada sí ọ̀dọ̀ ẹni tí ó jẹ wọ́n níyà, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò wá OLUWA àwọn ọmọ-ogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia na kọ yipada si ẹniti o lù wọn, bẹ̃ni nwọn kò wá Oluwa awọn ọmọ-ogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn náà kò tí ì yípadà sí ẹni náà tí ó lù wọ́n bẹ́ẹ̀ ní wọ́n kò wá OLÚWA àwọn ọmọ-ogun.