Isaiah 9:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n ń já nǹkan gbà lọ́tùn-ún, wọ́n ń jẹ ẹ́, sibẹ ebi ń pa wọ́n. Wọ́n ń jẹ àjẹrun lósì, sibẹ wọn kò yó, àwọn eniyan sì ń pa ara wọn jẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On o si jajẹ li ọwọ́ ọ̀tun, ebi o si pa a; on o si jẹ li ọwọ́ osì; nwọn kì yio si yo: olukuluku enia yio si jẹ ẹran-ara apa rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní apá ọ̀tún wọn yóò jẹrun, síbẹ̀ ebi yóò sì máa pa wọ́n, ní apá òsì, wọn yóò jẹ ṣùgbọ́n, kò ní tẹ́wọn lọ́rùn. Ẹnìkọ̀ọ̀kan yóò sì máa jẹ ẹran-ara ọmọ rẹ̀.