Jeremiah 10:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Òmùgọ̀ ni gbogbo eniyan jẹ́, wọn kò sì ní ìmọ̀; gbogbo àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà ni àwọn oriṣa wọn dójútì, nítorí pé irọ́ ló wà nídìí àwọn ère wọn; kò sí èémí ninu wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aṣiwere ni gbogbo enia nitori oye kò si: oju tì olukuluku alagbẹdẹ niwaju ere rẹ̀, nitori ère didà rẹ̀ eke ni, kò si sí ẹmi ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ènìyàn jẹ́ aláìlóye àti aláìnímọ̀, ojú sì ti gbogbo alágbára pẹ̀lú ère rẹ̀, èrú ni ère rẹ̀, kò sì sí ẹ̀mí nínú wọn.