Jeremiah 10:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìpín Jakọbu kò rí bí àwọn wọnyi, nítorí òun ló dá ohun gbogbo, Israẹli sì ni ẹ̀yà tí ó yàn, gẹ́gẹ́ bí ìní rẹ̀; OLUWA àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ipin Jakobu kò si dabi wọn nitori on ni iṣe Ẹlẹda ohun gbogbo; Israeli si ni ẹya ijogun rẹ̀: Oluwa awọn ọmọ-ogun li orukọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó bá jẹ́ ìpín Jákọ́bù kò sì dàbí èyí, nítorí òun ni ó ṣẹ̀dá ohun gbogbo àti Ísírẹ́lì tí ó jẹ́ ẹ̀yà ìjogún rẹ̀. OLÚWA àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.