Jeremiah 10:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo gbé, nítorí mo fara gbọgbẹ́! Ọgbẹ́ náà sì pọ̀. Ṣugbọn mo sọ fún ara mi pé, “Ìyà gan-an ni èyí jẹ́ fún mi, mo sì gbọdọ̀ fara dà á.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egbe ni fun mi nitori ipalara mi! ọgbẹ mi pọ̀: ṣugbọn mo wipe, nitõtọ ìya mi ni eyi, emi o si rù u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ègbé ni fún mi nítorí ìpalára mi! Ọgbẹ́ mi jẹ́ èyí tí kò lè sàn, bẹ́ẹ̀ ni mọ sọ fún ara mi, “Èyí ni àìsàn mi, mo sì gbọdọ̀ fi orí tì í.”