Jeremiah 10:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ní, “Ẹ má kọ́ àṣà àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, ẹ má sì páyà nítorí àwọn àmì ojú ọ̀run, bí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn tilẹ̀ ń páyà nítorí wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa wi, Ẹ máṣe kọ́ ìwa awọn keferi, ki àmi ọrun ki o má si dãmu nyin, nitoripe, nwọn ndamu awọn orilẹ-ède.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni ohun tí OLÚWA wí: “Má se tọ ọ̀nà àwọn orílẹ̀ èdè tàbí kí ẹ jẹ́ kí àmù òfuurufú dààmú yín, nítorí pé wọ́n ń dààmú orílẹ̀ èdè.