Jeremiah 10:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ gbọ́ àhesọ ọ̀rọ̀ kan! Ó ń tàn kálẹ̀! Ìdàrúdàpọ̀ ńlá ń bọ̀ láti ilẹ̀ àríwá, tí yóo sọ àwọn ìlú Juda di ahoro yóo sì di ibùgbé àwọn ajáko.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sa wò o, ariwo igbe ti de, ati irukerudo nla lati ilẹ ariwa wá, lati sọ ilu Judah di ahoro, ati iho ọwawa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fetísílẹ̀; ariwo ìdàrúdàpọ̀ ńlá náà ń bọ̀ láti ilẹ̀ àríwá, yóò sì sọ ìlú Júdà di ahoro àti ihò jàkùmọ̀