Jeremiah 10:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Tọ́ mi sọ́nà, OLUWA, ṣugbọn lọ́nà ẹ̀tọ́ ni kí o bá mi wí, kì í ṣe pẹlu ibinu rẹ, kí o má baà sọ mí di ẹni ilẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa kilọ fun mi, ṣugbon ni idajọ ni, ki o máṣe ni ibinu rẹ, ki iwọ ki o má sọ mi di asan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tún mi ṣe OLÚWA, pẹ̀lú ìdájọ́ nìkan kí o má sì ṣe é nínú ìbínú rẹ. Kí ìwọ má ṣe sọ mí di òfo.