Jeremiah 10:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí pé irọ́ ló wà nídìí àwọn àṣà wọn. Wọn á gé igi ninu igbó, agbẹ́gilére á fi àáké gbẹ́ ẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori asan ni ilana awọn orilẹ-ède; nitori igi ti a ke lati igbo ni iṣẹ ọwọ oniṣọna ati ti ãke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé asán ni asà àwọn ènìyàn, wọ́n gé igi láti inú igbó, oníṣẹ́-ọnà sì gbẹ́ ẹ pẹ̀lú àáké rẹ̀.