Jeremiah 10:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ, ìwọ ọba àwọn orílẹ̀-èdè? Nítorí ẹ̀tọ́ rẹ ni; kò sì sí ẹni tí ó gbọ́n tó ọ láàrin àwọn ọlọ́gbọ́n tí wọ́n wà ní àwọn orílẹ̀-èdè, ati ni gbogbo ìjọba wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tani kì ba bẹ̀ru rẹ, Iwọ Ọba orilẹ-ède? nitori tirẹ ni o jasi; kò si ninu awọn ọlọgbọ́n orilẹ-ède, ati gbogbo ijọba wọn, kò si ẹniti o dabi Iwọ!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ta ni kò yẹ kí ó bẹ̀rù rẹ Ọba àwọn orílẹ̀ èdè? Nítorí tìrẹ ni, láàrin àwọn ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní orílẹ̀ èdè àti gbogbo ìjọba wọn, kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ.