Jeremiah 10:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Aláìmọ̀kan ati òmùgọ̀ ni gbogbo wọn, ère kò lè kọ́ eniyan lọ́gbọ́n, nítorí igi lásán ni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nwọn jumọ ṣe ope ati aṣiwere; ìti igi ni ẹkọ́ ohun asan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo wọn jẹ́ aláìlóye àti òpè, wọ́n ń kọ́ ẹ̀kọ́ àwọn ère igi tí kò ní láárí