Jeremiah 12:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n sọ ọ́ di ahoro, ilẹ̀ pàápàá ń ráhùn sí mi. Wọ́n ti sọ gbogbo ilẹ̀ náà di ahoro, ṣugbọn ẹnikẹ́ni kò bìkítà fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti sọ ọ di ahoro, o ṣọ̀fọ fun mi bi ahoro: gbogbo ilẹ ti di ahoro, nitori ti kò si ẹnikan ti o rò li ọkàn rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A ó sọ ọ́ di aṣálẹ̀ ilẹ̀ tí kò wúlò níwájú mi, gbogbo ilẹ̀ ni yóò di ahoro nítorí kò sí ẹnìkankan tí yóò náání.