Jeremiah 13:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ti sé ìlẹ̀kùn odi àwọn ìlú ilẹ̀ Nẹgẹbu kò sì sí ẹni tí yóo ṣí wọn. A ti kó gbogbo Juda lọ sí ìgbèkùn, gbogbo wọn pátá ni a ti kó lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilu gusu wọnni ni a o si mọ, kò si ẹnikan ti yio ṣe wọn: a o kó Judah lọ ni igbekun gbogbo rẹ̀, a o kó wọn lọ patapata ni igbekun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn orílẹ̀ èdè tí ó wà ní Négéfì ni à ó tì pa, kò sì ní sí ẹnikẹ́ni láti sí wọn. Gbogbo Júdà ni a ó kó lọ sí ilẹ̀ ìgbèkùn, gbogbo wọn ni a ó kó lọ pátapáta.