Jeremiah 17:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ní, “Gègé irin ni a fi kọ ẹ̀ṣẹ̀ Juda sílẹ̀ gègé òkúta dayamọndi ni a sì fi kọ ọ́ sí ọkàn yín, ati sí ara ìwo ara pẹpẹ wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ̀ṢẸ Juda ni a fi kalamu irin kọ, a fi ṣonṣo okuta adamante gbẹ ẹ sori walã aiya wọn, ati sori iwo pẹpẹ nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹ̀ṣẹ̀ Júdà ni a fi ṣóóṣó irin kọ sílẹ̀ èyí tí ó hàn ketekete pẹ̀lú ẹnu ṣóróṣóró sí oókan àyà wọn, àti lórí àwọn ìwo tó wà lórí pẹpẹ wọn.