Jeremiah 17:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
níwọ̀n ìgbà tí àwọn ọmọ yín bá ń ranti àwọn pẹpẹ yín, ati àwọn oriṣa Aṣera yín, tí ẹ rì mọ́ ẹ̀gbẹ́ gbogbo igi tútù, ati lórí àwọn òkè gíga;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi awọn ọmọ wọn ba ranti pẹpẹ wọn, ati ere òriṣa wọn, lẹba igi tutu, ati ibi giga wọnni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kódà àwọn ọmọ wọn rántí pẹpẹ àti òpó Áṣérà lẹ́bàá igi tí ó tẹ́ rẹrẹ àti àwọn òkè gíga.