Jeremiah 17:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó dàbí igbó ṣúúrú ninu aṣálẹ̀, nǹkan rere kan kò lè ṣẹlẹ̀ sí i. Ninu ilẹ̀ gbígbẹ, ninu aṣálẹ̀ ni ó wà, ninu ilẹ̀ iyọ̀ tí ẹnikẹ́ni kò lè gbé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe yio dabi alaini ni aginju, ti kò si ri pe rere mbọ̀: ṣugbọn yio gbe ibi iyangbẹ ilẹ wọnni ni aginju, ilẹ iyọ̀ ti a kì igbe inu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yóò dàbí igbó tí ó wà ní ilẹ̀ aláìlọ́ràá, kò ní rí ire, nígbà tí ó bá dé yóò máa gbé ní ibi ìyàngbẹ ilẹ̀ ihà, ní ilẹ̀ iyọ̀ tí ẹnikẹ́ni kò gbé.