Jeremiah 18:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà OLUWA ní, “Ẹ bèèrè láàrin gbogbo orílẹ̀-èdè, bí ẹnikẹ́ni bá gbọ́ irú rẹ̀ rí. Israẹli ti ṣe ohun tó burú gan-an.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina bayi li Oluwa wí, Ẹ sa bère ninu awọn orilẹ-ède, tani gbọ́ iru ohun wọnni: wundia Israeli ti ṣe ohun kan ti o buru jayi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà báyìí ni OLÚWA wí: “Ẹ bèèrè nínú orílẹ̀ èdè, ẹni tí ó bá ti gbọ́ irú nǹkan wọ̀nyí ri? Ohun tí ó burú gidi ni wúndíá Ísírẹ́lì ti ṣe.