Jeremiah 18:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo fọ́n wọn ká níwájú ọ̀tá bí ẹ̀fúùfù ìlà oòrùn. Ẹ̀yìn ni n óo kọ sí wọn lọ́jọ́ àjálù, wọn kò ní rí ojú mi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o tú wọn ka gẹgẹ bi ẹ̀fufu ila-õrùn niwaju ọta wọn; emi o kọ ẹ̀hin mi si wọn, kì yio ṣe oju mi, ni ọjọ iparun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gẹ́gẹ́ bí afẹ́fẹ́ láti ìlà oorùn, Èmi yóò tú wọn ká lójú àwọn ọ̀tá wọn. Èmi yóò sì kọ ẹ̀yìn sí wọn, n kì yóò kọjú sí wọn ní ọjọ́ àjálù wọn.”