Jeremiah 2:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà kí ẹ̀rù kí ó bà ọ́, ìwọ ọ̀run, kí o wárìrì, kí gbogbo nǹkan dàrú mọ́ ọ lójú.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki ẹnu ki o ya ọrun nitori eyi, ki o si dãmu, ki o si di gbigbẹ, li Oluwa wi!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn mi ti dẹ́sẹ̀ méjì kí ẹ sì wárìrì pẹ̀lú ìbẹ̀rù ńlá,” ni OLÚWA wí.