Jeremiah 2:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn kinniun ti bú mọ́ ọn, wọ́n bú ramúramù. Wọ́n sọ ilẹ̀ rẹ̀ di ahoro. Àwọn ìlú rẹ̀ sì ti tú, wọ́n ti wó palẹ̀, láìsí eniyan tí ń gbé inú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ kiniun ke ramuramu lori rẹ̀, nwọn si bú, nwọn si sọ ilẹ rẹ̀ di ahoro, ilu rẹ̀ li a fi jona li aini olugbe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn kìnnìún ké ramúramú wọ́n sì ń bú mọ́ wọn wọ́n ti fi ilẹ̀ rẹ̀ ṣòfò Ìlú rẹ̀ ti di jíjóná, ó sì ti di ìkọ̀sílẹ̀.