Jeremiah 2:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bákan náà, àwọn ará Memfisi ati Tapanhesi ti fọ́ adé orí rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Nofi ati ti Tafanesi pẹlu ti jẹ agbari rẹ;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bákan náà, àwọn ọkùnrin Mémífísì àti Táfánésì wọ́n ti fa adé orí rẹ yọ.