Jeremiah 2:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí ni èrè tí ẹ rí nígbà tí ẹ lọ sí Ijipti, tí ẹ lọ mu omi odò Naili, àbí kí ni èrè tí ẹ gbà bọ̀ nígbà tí ẹ lọ sí Asiria, tí ẹ lọ mu omi odò Yufurate.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ nisisiyi kíni iwọ ni iṣe ni ipa-ọ̀na Egipti, lati mu omi Sihori? tabi kini iwọ ni iṣe ni ipa-ọ̀na Assiria lati mu omi odò rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ló dé tí o ṣe wá lọ Éjíbítì láti lọ mu omi ní Síhórì? Kí ló dé tí o sì fi lọ sí Àsíríà láti lọ mu omi ni odò Yúfúrátè náà