Jeremiah 2:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ẹ tilẹ̀ fi eérú fọ ara yín, tí ẹ sì fi ọpọlọpọ ọṣẹ wẹ̀, sibẹ, àbààwọ́n ẹ̀bi yín wà níwájú mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori iwọ iba wẹ ara rẹ ni ẽru, ki o si mu ọṣẹ pupọ, ẽri ni ẹ̀ṣẹ rẹ niwaju mi sibẹsibẹ, li Oluwa Ọlọrun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé o wẹ ara rẹ pẹ̀lú sódà tí o sì lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọṣẹ àbàwọ́n àìṣedéédéé rẹ sì ń bọ̀ níwájú mi,” ni OLÚWA Àwọn ọmọ ogun wí.