Jeremiah 2:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Má rìn láìwọ bàtà, Israẹli, má sì jẹ́ kí òùngbẹ gbẹ ọ́. Ṣugbọn o sọ pé, ‘Kò sí ìrètí, nítorí àjèjì oriṣa ni mo fẹ́, n óo sì wá wọn kiri.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Da ẹsẹ̀ rẹ duro ni aiwọ bàta, ati ọfun rẹ ninu ongbẹ: ṣugbọn iwọ wipe, lasan ni! bẹ̃kọ, nitoriti emi ti fẹ awọn alejo, awọn li emi o tọ̀ lẹhin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe sáré títí ẹṣẹ̀ yín yóò fi wà ní ìhòòhò, tí ahọ́n yín yóò sì gbẹ. Ṣùgbọ́n ìwọ wí pé, ‘Kò nílò! Èmi fẹ́ràn àwọn ọlọ́run àjèjì, èmi yóò sì lépa wọn lọ.’