Jeremiah 2:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Israẹli jẹ́ mímọ́ fún OLUWA Òun ni àkọ́so èso rẹ̀. Gbogbo àwọn tí wọ́n jẹ ninu àkọ́so èso yìí di ẹlẹ́bi; ibi sì dé bá wọn. Èmi OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mimọ́ ni Israeli fun Oluwa, akọso eso oko rẹ̀, ẹnikẹni ti o fi jẹ yio jẹbi; ibi yio si wá si ori wọn, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ísírẹ́lì jẹ́ mímọ́ sí OLÚWA, àkọ́kọ́ èṣo ìkórè rẹ̀, gbogbo ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ run ni a ó dá lẹ́bi, ìpọ́njú yóò dé bá wọn,’ ” bẹ́ẹ̀ ni OLÚWA wí.