Jeremiah 2:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀jẹ̀ àwọn talaka tí kò ṣẹ̀, wà létí aṣọ yín; bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò bá wọn níbi tí wọ́n ti ń fọ́lé. Gbogbo èyí wà bẹ́ẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu ẹjẹ ẹmi awọn talaka ati alaiṣẹ mbẹ lara aṣọ rẹ, iwọ kò ri wọn nibi irunlẹ wọle, ṣugbọn lara gbogbo wọnyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lórí aṣọ rẹ ni wọ́n bá ẹ̀jẹ̀ àwọn talákà aláìṣẹ̀ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò ká wọn níbi tí wọ́n ti ń rùn wọlé