Jeremiah 2:36 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀ ń fi ara yín wọ́lẹ̀ káàkiri; ẹ̀ ń yà síhìn-ín sọ́hùn-ún! Bí Asiria ti dójú tì yín, bẹ́ẹ̀ ni Ijipti náà yóo dójú tì yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẽṣe ti iwọ ṣe ati yi ọ̀na rẹ pada bẹ̃, oju yio tì ọ pẹlu fun Egipti, gẹgẹ bi oju ti tì ọ fun Assiria.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ló dé tí o fi ń lọ káàkiri láti yí ọ̀nà rẹ padà? Éjíbítì yóò dójú tì ọ́ gẹ́gẹ́ bí i ti Ásíríà