Jeremiah 2:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ óo ká ọwọ́ lérí ni nígbà tí ẹ óo bá jáde níbẹ̀. Nítorí OLUWA ti kọ àwọn tí ẹ gbójúlé, wọn kò sì ní ṣe yín níre.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lõtọ iwọ o kuro lọdọ rẹ̀, iwọ o si ka ọwọ le ori, nitori Oluwa ti kọ̀ awọn onigbẹkẹle rẹ, iwọ kì yio si ṣe rere ninu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ yóò sì fi ibẹ̀ sílẹ̀ pẹ̀lú ọwọ ìkáwọ́ lórí rẹ ní orí rẹ nítorí pé OLÚWA ti kọ̀ àwọn tí ìwọ gbẹ́kẹ̀lé, kì yóò sí ìrànlọ́wọ́ kankan fún ọ láti ọ̀dọ̀ wọn wá.