Jeremiah 2:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Nítorí náà, mò ń ba yín rojọ́, n óo sì tún bá arọmọdọmọ yín rojọ́ pẹlu.” OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina, Emi o ba nyin jà, li Oluwa wi, Emi o si ba atọmọde-ọmọ nyin jà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí náà, mo fi ẹ̀sùn kàn yín lẹ́ẹ́kan síi,” ni OLÚWA wí. “Èmi ó sì fi ẹ̀sùn kan àwọn ọmọ ọwọ́ rẹ