Jeremiah 20:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Paṣuri alufaa, ọmọ Imeri, tí ó jẹ́ olórí àwọn olùṣọ́ ilé OLUWA, gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jeremaya ń sọ,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NJẸ Paṣuri, ọmọ Immeri, alufa, ti iṣe olori olutọju ni ile Oluwa, gbọ́ pe, Jeremiah sọ asọtẹlẹ ohun wọnyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìgbà tí àlùfáà Pásúrì ọmọkùnrin Ímímérì olórí àwọn ìjòyè Tẹ́ḿpìlì OLÚWA gbọ́ tí Jeremáyà ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ nǹkan wọ̀nyí.