Jeremiah 21:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní, “Sọ fún àwọn eniyan yìí pé èmi OLUWA ni mo la ọ̀nà meji níwájú wọn: ọ̀nà ìyè ati ọ̀nà ikú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati fun enia yi ni ki iwọ ki o wipe, Bayi li Oluwa wi; Sa wò o, emi fi ọ̀na ìye ati ọ̀na ikú lelẹ niwaju nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Síwájú síi, sọ fún àwọn ènìyàn, ‘Èyí ni ọ̀rọ̀ OLÚWA tí ó sọ: Wò ó, Èmi ń fi ọ̀nà ìyè àti ikú hàn yín.