Jeremiah 22:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ẹ gun orí òkè Lẹbanoni lọ, kí ẹ kígbe. Ẹ dúró lórí òkè Baṣani, kí ẹ pariwo gidigidi, ẹ kígbe láti orí òkè Abarimu, nítorí pé a ti pa gbogbo àwọn alájọṣe yín run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Goke lọ si Lebanoni, ki o si ke, ki o si gbe ohùn rẹ soke ni Baṣani, ki o kigbe lati Abarimu, nitori a ti ṣẹ́ gbogbo olufẹ rẹ tutu,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Gòkè lọ sí Lẹ́bánónì, kígbe síta kí a sì gbọ́ ohùn rẹ ní Básánì, kí o kígbe sókè láti Ábárímù, nítorí a ti run gbogbo àwọn olùfẹ́ rẹ túútúú.