Jeremiah 22:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo kó àwọn apanirun tí yóo pa ọ́ run wá, olukuluku yóo wá pẹlu ohun ìjà rẹ̀. Wọn óo gé àwọn tí wọn dára jùlọ ninu àwọn igi Kedari yín, wọn óo sì sun wọ́n níná.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o ya awọn apanirun sọtọ fun ọ, olukuluku pẹlu ihamọra rẹ̀: nwọn o si ke aṣayan igi kedari rẹ lulẹ, nwọn o si sọ wọn sinu iná.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ó rán apanirun sí ọ olúkúlùkù ọkùnrin pẹ̀lú ohun ìjà rẹ̀, wọn yóò sì gé àsànyàn igi kédárì rẹ lulẹ̀, wọn ó sì kó wọn jù sínú iná.