Jeremiah 23:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ati wolii, ati alufaa, ìwà burúkú ni wọ́n ń hù, ní ilé mi pàápàá mo rí iṣẹ́ ibi wọn, èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori, ati woli ati alufa, nwọn bajẹ; pẹlupẹlu ninu ile mi ni mo ri ìwa-buburu wọn, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Wòlíì àti àlùfáà kò gbé ìgbé ayé ìwàbí Ọlọ́run; kódà nínú Tẹ́ḿpìlì mi ni mo rí ìwà búburú wọn,” ni OLÚWA wí.