Jeremiah 23:38 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn bí ẹ bá mẹ́nu ba “Ẹrù OLUWA,” lẹ́yìn tí mo ti ranṣẹ si yín pé ẹ kò gbọdọ̀ mẹ́nu bà á mọ́,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn bi ẹnyin ba wipe, ọ̀rọ-wuwo Oluwa, nitorina, bayi li Oluwa wi, nitori ẹnyin nsọ ọ̀rọ yi pe, ọ̀rọ-wuwo Oluwa ti emi si ranṣẹ si nyin pe ki ẹ máṣe wipe: ọ̀rọ-wuwọ Oluwa;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀yin ń sọ wí pé, ‘Èyí ni ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ OLÚWA,’ èyí ni ohun tí OLÚWA sọ: Ó ń lo ọ̀rọ̀ yìí, ‘Èyí ni ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ OLÚWA,’ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo sọ fún un yín láti má ṣe gbà á, ‘Èyí ni ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ OLÚWA.’