Jeremiah 24:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ní òun óo sọ wọ́n di ẹni àríbẹ̀rù fún gbogbo ìjọba ayé. Wọn óo di ẹni ẹ̀gàn, ẹni ẹ̀sín, ẹni yẹ̀yẹ́ ati ẹni tí a fi ń ṣẹ́ èpè ní gbogbo ibi tí òun óo tì wọ́n lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o fi wọn fun iwọsi ati fun ibi ninu gbogbo ijọba aiye, lati di ìtiju, owe, ẹsin, ati ẹ̀gan ni ibi gbogbo, ti emi o le wọn si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò sọ wọ́n di ìwọ̀sí àti ẹni ibi sí gbogbo ìjọba ayé, ẹni ẹ̀sín àti ẹni ẹ̀tẹ́, ẹni àbùkù àti ẹni èpè ní ibi gbogbo tí Èmi bá lé wọn sí.