Jeremiah 25:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ati gbogbo àwọn ọba Tire, ati àwọn ọba Sidoni, ati gbogbo àwọn ọba erékùṣù tí ó wà ní òdìkejì òkun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati gbogbo awọn ọba Tire, ati gbogbo awọn ọba Sidoni, ati awọn ọba erekuṣu wọnni ti mbẹ ni ikọja okun,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn Ọba Tirè àti Sídónì; gbogbo àwọn Ọba erékùṣù wọ̀n-ọn-nì tí ń bẹ ní ìkọjá òkun.