Jeremiah 25:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo fún Dedani mu, ati Tema, ati Busi ati gbogbo àwọn tí wọn ń gé ẹsẹ̀ irun wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dedani, ati Tema, ati Busi, ati gbogbo awọn ti nda òṣu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dédánì, Témà, Búsì àti gbogbo àwọn tí ń gbé lọ́nà jínjìn réré.