Jeremiah 25:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo fún gbogbo àwọn ọba Arabia mu ati gbogbo àwọn ọba oríṣìíríṣìí ẹ̀yà tí wọn ń gbé aṣálẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati gbogbo awọn ọba Arabia, pẹlu awọn ọba awọn enia ajeji ti ngbe inu aginju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn Ọba Árábíà àti àwọn Ọba àwọn àjòjì ènìyàn tí ń gbé inú ihà.